La Religión Yorùbá
LAS RELIGIONES DEL PUEBLO YORÙBÁ / ÀWỌN Ẹ̀SÌN NÍLẸ̀ YORÙBÁ Kí àwọn òyìnbó àti mùsùlùmí tó dé ilẹ̀ yorùbá ni àwọn yorùbá ti ní ẹ̀sìn ti wọn ti wọ́n ń pè ní òrìṣà. Ọ̀kanlénírinwó òrìṣà ló wà nílẹ̀ yorùbá. Ànfàní tó wà láàárín ẹ̀sìn yorùbá kìí ṣe kékeré rárá. Pẹ̀lú ayọ̀ ati ìrẹ́pọ̀ ni gbogbo …