LAS RELIGIONES DEL PUEBLO YORÙBÁ / ÀWỌN Ẹ̀SÌN NÍLẸ̀ YORÙBÁ
Kí àwọn òyìnbó àti mùsùlùmí tó dé ilẹ̀ yorùbá ni àwọn yorùbá ti ní ẹ̀sìn ti wọn ti wọ́n ń pè ní òrìṣà. Ọ̀kanlénírinwó òrìṣà ló wà nílẹ̀ yorùbá. Ànfàní tó wà láàárín ẹ̀sìn yorùbá kìí ṣe kékeré rárá. Pẹ̀lú ayọ̀ ati ìrẹ́pọ̀ ni gbogbo àwọn òrìṣà yorùbá fi ń gbé pẹ̀lú ara wọn. Ṣàngó kò bá Ògún jà, bẹ́ẹ̀ ni Ifá kò bá Ọ̀ṣun ṣọ̀tẹ̀.
Lásìkò ọdún egúngún gbogbo ará ìlú a bá àwọn eléegún ṣẹ̀yẹ. Tó bá sì di àsìkò ọdún Ṣàngó, gbogbo ará ìlú a wọ́ jáde láti bá àwọn oníṣàngó ṣàríya.
Díẹ̀ nínú àwọn òrìṣà ilẹ̀ yorùbá pẹ̀lú oríkì wọn nìyìí.
ALGUNOS DE LOS ÒRÌṢÀ DEL PUEBLO YORÙBÁ
Ifá es el camino de la luz y su oráculo, el más importante de los que componen la religión yorùbá. La palabra Ifá se refiere a la entidad mística Ifá u Ọ̀rúnmìlà, considerado como la divinidad de la sabiduría y del desarrollo intelectual. La adivinación del oráculo Ifá no depende de una persona que tiene poderes misteriosos o proféticos, sino de un sistema de signos que son interpretados por un adivino, el sacerdote Ifá o Babaláwo, literalmente «el padre de los secretos y/o de la adivinación». Se aplica el sistema de adivinación Ifá cada vez que se ha de tomar una decisión individual o colectiva importante.